
Rwanda fa’ri ga!
Photo credit: the Telegraph Orile ede Rwanda ti so wipe toro to yo, orile ede United Kingdom ko le rigba ninu owo to da awon orile ede mejeji po.Dokita Doris Picard ti owa ni ile ise ofin ijoba Rwanda so pe ilu Rwanda ti ko ipa tie.Ijoba ana lori ile ede United Kingdom tin gbero lati ma fi…